iseyin

Aja torini ti njuru, to wa di Aja to nrini saa.
Bio Ba Ni'di, Obinrin Ki Jee Kumolu. Were sun, were sun, bi were ba sun kan'giri, yoo yi'ju pada. Oro nbo, yo taba ara Ile, Yoo Taba ara Oko.
Ija nbo Pelu. Igba die naa lokun. Mo see ranti ni, pe Ojuboro o se Gbomo Lowo ekuro. Eku Oju Lona. AJIBOLA AFOLAYAN YUSUFF.
Olori Awon Akeeko, Ijoba Ibile Iseyin.